Here is this awesome worship song from Michael Akingbala titled “Jesu Tete De”, Michael is a musicologist, a worship leader a songwriter, composer, He has written several powerful songs and he’s still doing valiantly well in the ministry.
He is a member of the RCCG National Mass Choir and also the leader of a band known as “SOULSSEEKER” which is in accordance with the vision of RCCG WORLDWIDE. He is a child of GOD
FaceBook; Michael Akingbala
twitter.com/akingbalamike
Instagram ; Michael Akingbala
LYRICS:
Chorus:
call: jesu jesu jesu, te te de
Resp: jesu jesu jesu, te te de
Call: Jesu jesu jesu, omi je jabo
Resp: Jesu jesu jesu, omi je jabo
Verse 1:
iwo lo to, iwo looto
iwo loonto, iwo gangan lotito
yagboyaju okunri ogun
adagba ma paro ooye
oba to tele bi enu teni
ota sonmo beeni taaso
ogbigba ti gba alailara
baba mi aja ma jebi
aja ma fi ti bon se
owo sokoto kembe re bi ija
to ba ti e wo nko ooo?
kini grandfather enikankan yi o se x2
aleni ba lo na, lai puro loju kan
oro ti gbenu omo eniyan to n fohun
oba ti kin ku, oba tiki n sha
oba ti ki ti, ti kin di baje
Chorus:
call: jesu jesu jesu, te te de
Resp: jesu jesu jesu, te te de
Call: Jesu jesu jesu, omi je jabo
Resp: Jesu jesu jesu, omi je jabo
Download “Jesu te te de” michael-akingbala.mp3 – Downloaded 2311 times – 10 MB